Aula 6 – ODU OGBE ODI

Este odu explica a importância de Ogun no uso do obé e a necessidade de sacrifícios, marcando o acordo de Orunmilá com Ogun.

Abowaba awo ode orun

A d’ífá fún Ogun

Lojo tó nbà wá sodé ayé

Ó fi orí /e odo Orunmila

Kí ó le mo bi irin ajo naa

Se má ari ó ní agbara

Atí gbà emi fún íjiya

olorun ati Òrìsà

Won ní kó rubo

Kó tó lo si ajo

Kó fi adá rubo

Si Òrúnmìlà

Ki Òrúnmìlà le fún

Ati àwon omo re

Agbara atí gbà emí

Gegebi etutu si Òrìsà

Ati egún

Orunmila so wí pe

Bo se wà lati atete kó se

Ti Bàbàláwo atí iyaonifá

Bà bere Ifá

Atí asé lowo ogun

Fun etutu

Àwon Orisà

Ogun rubo

ó fún Òrúnmìlà lo be

Oná sí la fún ó je pe

Àwon omo Òrúnmìlà ni

Yó ó sa lati iyaonifa

Ní ase

Won nkorin

Ogun fún wón ní ase

Lati odo Òrúnmìlà pe

Ti won kó ba rubo

Kó ní si ibukun

Atí alafia laye

Abowaba awo ode Orun

A d’ífá fun Orunmila

Kó ní ipin

Pelu Orunmila ko le

Dí bàbálawo atí asiri

Àwon omo Orunmila

Agbara àwon olugbe aye

Ní yó ó fún won ni

Ominira ojuse ogun ni

Pelú Orunmila  náa ní

Agbara atí rubo

Gbá emi fún ijaja

Gbara àwón tó ntele

Atí áwon tó ntele

Olorun

Àwon omo Orunmila

Gbà se lówo ogun

Atí lkin Ifa

Ní gbatí Orunmila

Se itefá fún won

Won gbà ase Orunmila

Tori pe won

lgbese otíto ji ó ji o

Orunmila fun niase

lru eyí tó fún ogun

Ohun lo so dí Bàbàláwo

Verso publicado por Apola.

TRADUÇÃO:

No dia em que vinha em direção a Terra

Ele disse para ir para a casa de Òrúnmìlà

Ifá disse-lhe para ter sucesso na sua missão

Eu era e disse que ele tinha o poder

Leve a vida

Como punição de OLORUN

E como um sacrifício para Òrìsà

Ele deve ser o sacrifício feito

Antes de sua partida

E oferecer Òrúnmìlà

sua faca

Òrúnmìlà e

seus filhos e filhas sacerdotes

Pois receberam a autoridade

Para tirar a vida para o sacrifício

Òrìsà

Òrúnmìlà disse posteriormente

Bàbàláwos e iyaonífás

Ele foi iniciado em Ifá

Eles receberão autoridade Ògún

Òrìsà sacrifício e Ògún

Ògún fez sacrifício e entregou a faca para Òrúnmìlà

Missão foi bem sucedida

Para os filhos de Òrúnmìlà

Eles cuidam de sacrifício Òrìsà

Eles terão autoridade

Concessão que eu tornado

Sacerdotes Òrìsà

Eles cantaram que

RECEBERAM a autoridade

Òrúnmìlà

Deu-lhes

Filhos de Òrìsà.

Òrúnmìlà média

Sem sacrifício

Faria bênçãos.

error: O conteúdo é protegido!!